Oluporo Ikaomesi Ijenjeniwonran, D’Ifa fun Olodumare ti yio t’orun fimule mu ebora se….. Igare-Osule, gbogbo eriwo ni foribale fun alase ‘Ijinle Ohun Ife’………………… { ‘Oluporo Ikaomesi Ijenjeniwonran (Sealers Of Every Words & Languages), Divined for the Almighty God that initiated ...
Read More »Post of the Day !
I never once in my life regrets ever since I started listen to voice of OLODUMARE through IFA. Is the only way to hear the true/real voice of OLODUMARE try and see.
Read More »Awon foto lati ibi iwuye Oba Adeyeye Enitan, Ooni ti Ile-Ife (Apa-Keji)
Oba Babatunde Enitan Adeyeye Ogunwusi Ojaja II
Read More »Ile ejo to gaju lo ni yoo pari idaju iku Reverend King
Ile ejo to gaju nile yii ti kede ojo kerindinlogbon osu keji odun ti n bo (26/02/15) gege bi ojo ti igbejo adari ijo Christian Praying Assembly, Reverend Chukwuemeka Ezeugo, ti gbogbo eniyan mo si Reverend King yoo ma waye. ...
Read More »E kaabo si aafin Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi
E kaabo si aafin Ooni Adeyeye Enitan Ogunwus
Read More »“Oruko awon to ja Naijiria lole ko ni pe jade” – Buhari
Aare Buhari ti fi da awon omo Naijiria loju wi pe, laipe, awon oruko awon ojelu ti won ko owo Naijiria je ko ni pe di tite jade fun gbogbo aye. Gege bi oro re, eleyii to se nibi ipade ...
Read More »Oselu ipinle Oyo: Alao Akala ti wa ogbon mii da
Christopher Alao Akala ti wa ogbon mii da Nibayii ti Christopher Alao-Akala, eni odun marunlelogota (65) ti pinnu lati darapo mo egbe APC lati inu egbe Labour Party ni awon awuyewuye kan ti bere si ni jeyo jade. Lara awon ...
Read More »Iriri awon omuti: Ore meji ku, iketa fara pa
Gege bi oro awon Yooba,”eni Sango ba toju re wole, eni naa ko ni ba won bu oba Koso laelae.” Okunrin kan to pe ara re ni Cde Zenzele Nkosi lori FACEBOOK lo salaye ijamba moto to sele si i ...
Read More »Syrian Army backed with Russian air-support Liberates Latakia From Terrorists
Syrian Army backed with Russian air-support Liberates Latakia’s Border With Turkey From Terrorists Following week of battle, Syrian forces have wiped out al-Nusra Front terrorists from the sloping districts in the northern piece of Latakia area alongside the Syrian-Turkish border. ...
Read More »Video: Nigerian Man builds 2 Home Made Drones
This Nigerian Man Just Re-Invented two Home Made Drones and they work superbly well, I Think Government need to make an advisory group to encourage and empower this king of people. https://www.youtube.com/watch?v=50yaxxqC6G8
Read More »