The number of people who have died as a result of the coronavirus pandemic now exceeds 10 , 000 , according to an AFP tally based on official data at 1030 GMT Friday .
Read More »Ọ̀nà Jìbìtì 2
Ọ̀nà Jìbìtì 2Awon miiran maa n duro si opopona bi eni ti moto won baje. Won le mu omo ileewe kan tabi meji si egbe won gege bi eni to nilo iranlowo. Awon to ba duro ti won ti ko ...
Read More »Buhari bá ìpínlè̩ Eko ké̩dùn
Buhari bá ìpínlè̩ Eko ké̩dùn – Ìròyìn lati o̩wó̩ Yínká Àlàbí Ojo buruku esu gbomi mu ni ojo isinmi oni je fun awon ara agbegbe Amuwo Odofin ni adugbo FESTAC.Ijamba ina naa bere ni aago mesan-an aaro. Opa epo ni ...
Read More »Nítorí Àrùn Coronavirus Ìjọba Àpapọ̀ Ní Káwọn Arìnrìnàjò Láti Orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà, Gẹ̀ẹ́sì, Faransé Àtorilẹ̀èdè Mọ́kànlá Míràn O Gbélé Wọn
Bákan náà ni Ìjọba àpapọ̀ tún ṣàlàyé pé àṣẹ yìí ló bẹ̀rẹ̀ sí ní fi ẹsẹ̀ múlẹ̀, bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ Sátidé, ọjọ́ kọkànlélọ́gún oṣù kẹta ọdún 2020.
Read More »Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩
Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩– Iroyin lati Owo Akinwale Taophic. Latari iku odo agbaboolu, Chineme Martin’s, eni ti o pade iku ojiji ni abala akoko ifigagbaga ose ketalelogun liigi orileede wa Nigeria, NPFL, ti o waye laarin Nasarawa United ...
Read More »Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn wọ́gilé ìyọnípò Oshiomole gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC
Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn wọ́gilé ìyọnípò Oshiomole gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC
Read More »Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn
Arabinrin ti o sese ti ilu London de ni o bere si nii wuko ti o si n se kata. Ni eyi ti o mu ki o fara re sile fun ayewo coronavirus.
Read More »Ọ̀nà Jìbìtì
Bi ara ipede Radio Naigeria O.Y.O ni aye atijo, won ni, “Ifunra loogun agba, pasa ko funra, o ja sina, aja ko funra, aja jin, ti onile naa ko ba funra, ole ni yoo ko lo”. Eyi ni o difa fun gbogbo awa ti a maa n gbe moto lo si ibi inawo.
Read More »COVID-19: How to Prevent the spread of Coronavirus – Video #CoronaVirusUpdate
For Nigerians arriving from affected countries, PLEASE obey the authorities instructions & self-isolate for 14 days. Please. It’s not about whether you feel ill or not. It’s possible to have the virus & not feel any symptoms. If you know ...
Read More »China’s Richest man Jack Ma Donating Anti-Coronavirus Medical Supplies To All African Nations
China’s richest man Jack Ma has announced he was donating medical supplies to all African nations to combat COVID-19, the respiratory disease caused by the novel coronavirus.
Read More »