Toke Makinwa’s 30th birthday party last night. See a few pics bellow..
Tagged with: Toke Makinwa
Toke Makinwa sèsè dé sí orílè èdè South Africa láìpé yí gégé bí ó se ń rìn káàkiri àgbáyé láti di gbajúgbajà ònkòwé. Ìmúra rè yanilénu nígbà tí ó wo aso aláwò pupa férééfé (pink Gert Johan) àti bàtà tí a mò sí Calvin Klein isé owó Harvellastyles ni, ó wà lójú ònà tí ó ńlo sí TouchHD fún ìfi-òrò-wá ni -lénu -wò lórí redio. Nígbà tí ó jáde pèlú oba ilé-isé redio Tbo Touch. Toke ti wà ní ...