Home / Naija Gist / Metro life / Foto lati ibi ayeye ojo ibi Pasuma to waye lonii
pasuma

Foto lati ibi ayeye ojo ibi Pasuma to waye lonii

Wasiu Alabi Pasuma, Oganla Fuji 1, pe eni odun mejidinlaadota (48) lonii. Ayeye ojo-ibi IbaWasila waye ninu ile re to kale si Omole niluu Eko nibi ti awon eniyan Olorun, ore ati ojulumo ti pejo lati ba yo ayo ojo ibi re naa. Igba odun, odun kan ni fun Orobokibo Creator.  #HBDOganla

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

yoruba

Can we speak Yoruba language without code mixing? is it important?