Home / Art / Àṣà Oòduà / Foto: Saheed Osupa Mr Designer

Foto: Saheed Osupa Mr Designer

Awon eniyan oba ni Osupa ti mura tan lati gbe awo orin re tuntun jade. E le ka iroyin naa NIBI. Eniwee, mo sakiyesi wi pe awon aso okeere maa n mu oju osupa dabi odomode nigba ti awon aso ibile wa maa mu dabi baba agbalagba.

Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

Saheed Osupa n pada bo pelu Lord of Music

Oba orin, Saheed Osupa ti n mura lati ju awo orin tuntun kale sigboro ki odun yii to pari. Awo orin naa ni won pe ni Lord of Music eleyii ti yoo jade ninu osu December odun yii.