Ile ejo ti dajo iku fun Chonmanee Laphathanawat, eni ogbon (30) odun ni ilu Thailand pelu esun gbigbe ogun oloro cocaine ni orileede Thailand.
Omobirin yii ni won mu pelu bo se sin ogun-oloro ti won ti ro sinu kapusu (capsules) bi aadorin (70) si oju-ara ati inu iho idi re.
Ana, 27-08-2015, ni won da ejo omobirin naa.
Ki Oluwa oba dari gbogbo ese re jin-in.
E sora fun ogun-oloro. Ko Dara!
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


