*Emi ko ni ku saaju ojo ayo mi.*Emi ko ni fi ewon logba.*Iji aye ko ni gbe mi lo(Ase Edumare).
………….
#AKARA_IMORAN : Gbiyanju lati ni iwe iranti fun awon olooore re; ki o si gbiyanju lati fa iwe asise awon to se o ya. Ranti pe awon kan ni iwo naa se, ti won darijin iwo naa. Ayo ni ooo.
lati owo Aare Olasunkanmi Alani Agbasaga
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

