Home / Art / Àṣà Oòduà / Akékòó odún kerin tí ó rì s’ómi ní Yankari.

Akékòó odún kerin tí ó rì s’ómi ní Yankari.

Gabriel Emmanuel Chinoso, tí ó jé Akékòó olódún mérin tí se Akékòó eka èkó onímò nípa ohun amáyé rorùn tí a mò sí electrical engineering ní ilé-èkó gíga Tafawa Balewa university, Bauchi ni ati gbó wípé òkú sí inú odò ìwè ní Yankari.

Ó rì s’ómi nígbà tí ó n wè lówó ní ojó àìkú tí alukoro àwon olópàá tí a mò sí Dsp kamal Abubakar nàà ti jérìí si.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti