Arákùnrin kan tí ó wá láti Yenegoa ní ìpínlè Bayelsa, Bogilizibe Godwin Obiene, ti gbèrò láti se obè aláta yéríyérí abó kan léyìn ìgbà tí ó pa eran afayàfà tí ó je.
Arákùnrin tí inú rè n dùn yí pin sí orí èro ayélujára ( Facebook) tí ó sì ko síbè wípé “Obè aláta yéríyérí ti dé lè.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

