Home / Art / Àṣà Oòduà / Funke Akindele ti ya àwòrán tuntun.

Funke Akindele ti ya àwòrán tuntun.

Gbajúgbajà òsèré obìnrin orílè èdè Nàíjíríà, Funke Akindele ti gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tuntun ti ara rè tí ó sèsè yà níbi tí ó ti padà sí enu isé.
Sùgbón ìbéèrè ni wípé, sé ó ti bímo ni àbí báwo?
Níbi àwòrán tí ó pín, n se ni ó dàbí eni wípé ó ti Sanra si, súgbón mi ò rí oyún ní ikùn rè.
Mo rò wípé kì í se nkan tí mò n rò sha? àbí sé ohun tí mò n rò ni èyin náà n rò ni?

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete