Òsèré obìnrin orílè èdè Nàíjíríà tí ó tún jé ìyàwó 2baba tí ó jé olórin nlá, olorì Idibia dàbí egbin lo sí ibi ìgbéyàwó Banky W àti Adesua ní ojó ìsinmi tí ó kojá.
Mo dàgbà tán èwe wù mí, nse ni ó dàbí eni wípé ó tún n kéré si.
Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì lẹ́yìn tó lọ fún idanilẹkọ ní ilé ìtura Sunview nílùú Akure. Iyawo arakunrin naa salaye rẹ pe, ni ọjọ kẹrinlelogun oṣu Kẹjọ, ọdun 2025, ni ọkọ rẹ dagbere pe ohun n lọ fun idanilekọ kan n’iluu Akure, eyi ti wọn ...