Home / Art / Àṣà Oòduà / Oba ti ilè Benin, Ewuare,ti kalè sí Abuja pèlú àwon olóyè rè fún àbèwò pàtàkì.

Oba ti ilè Benin, Ewuare,ti kalè sí Abuja pèlú àwon olóyè rè fún àbèwò pàtàkì.

Oba ti ilè Benin, Aláse èkejì òrìsà, Oba Ewuare ti balè sí Abuja fún àbéwò pàtàkì. Oba tí àwon olóyè rè sìn lo sí Abuja ni won ti kí káàbò, àwon alága ìgbìmò egbé APC (All progressive Congress), John Oyegun ti di tòwòtòwò kí káàbò, bí ó ti gbìmò láti lo se àbéwò sí gbogbo gbò, gégé bí ó se so óní òun yó bèrè láti orí Ààre Muhammadu Buhari ní Aso Rock Villa ní ìlú Abuja.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti