Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó olùgbá bóòlù aláwòn ní Brooklyn, Quincy Acy àti àfésónà rè, Jessica Fuenten tí ó sèsè gbòde kan léyìn ìgbà tí inú arewà ìyàwó àfésónà sì ń dùn, so wípé àwon bèrè gégé bíi Òré tímótímó. Àtìgbà tí àwon ti fé ara àwon, àwon ń gbé pèlú ìdùnú gégé bí a ti ri nínú àwòrán ìsàlè yìí. E wo irú ìdùnú tí omobìnrin yí kò bá pàdánù tí kò bá gbà kí won fé ara won sùgbón tí won jo jé Òré Lásán …
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

