Àwòrán Oritsefemi àti Nabila Fash léyìn tí won se ìgbéyàwó ìbílè ní òwúrò tán kí ó tó di wípé won se ti alárédè. Oritsefemi àti ìyàwó rè tí tè síwájú fún ìgbéyàwó alárédè .
E wo Nabila Fash bí ó se dàbí egbin, nse ni ó dàbí kí èmi náà lo se ìgbéyàwó eléyìí tí gbogbo won kàn n se ìyàwó yí.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

