Home / Art / Àṣà Oòduà / Aworan Yii Kiise Aroso Rara !

Aworan Yii Kiise Aroso Rara !

Bi Mi O Tie Mo Iyawo, Sugbon Mo Mo Oko Pelu Ise-owo Re, Isele Aburu Yi Waye Ni Ilu Ilogbo Ota, Ni Ipinle Ogun. Oko (Morufu Olasoji) Nfi Esun Agbere Kan Iyawo Re Kehinde Olasoji, Pelu Igbonara, Oko Lu Iyawo Re Pa. Ti A Ba Ba Alara Wi, Ki A Ba Alero Wi, Boya Iro Ni Oko Pamo Iyawo Tabi Otito, O Ye Olorun Oba, Iwo Oko Tabi Iyawo Ile, Ti O Si Tun Nwo Ita, Lo Jawo, Nitoripe Kosi Ere Nidi Ise Agbere, Bikose Iku, Besini Iwo Okunrin Alara Gbigbana, Mu Suuru, Ti O Bati Ka Iyawo Re Fun Ra Re Nidi Agbere, Fun Ni Iwo Ikosile Gegebi Bibeli Tiwi. Sebi Eri Ise Esu, Boya Lati Igbati Wonti Dele Aye, Won Ko Jade Ninu Iwe-iroyin Ri, O Wa Je Igbati Won Fi Aye Sile Fesu. Eledumare Ti O Nba Eda Gberu, Yio Bawon Toju Awon Omo Won Meteta, Ogun kogun Koni Tule Wa ka Tabi Dale Wa Ru , Awon Omo Wa Koni Di Omo Orukan Ojiji 

Ase!

 

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Ọbàtálá

A kú ọ̀sẹ́ Òrìṣà [Ọbàtálá]

Éèpà ÒrìṣàMo ṣẹbà aṣẹ̀dá!Mo ṣèbà Ọba àlà funfunỌba ńlá o jíreWa túnbọ̀ tàlà bòmí,Àlábàláṣẹ! Happy Ọbatala worship day Obatala #Oriṣanla #Ancestor #Yoruba#Decolonization