Home / Art / Àṣà Oòduà / Babajide Sanwoolu àti Obafemi Hamzat pàdé àwon ìlúmòóká Òsèré.

Babajide Sanwoolu àti Obafemi Hamzat pàdé àwon ìlúmòóká Òsèré.

Babajide Sanwoolu àti Obafemi Hamzat pàdé àwon ìlúmòóká Òsèré.
Omo egbé APC tí won yàn láti díje fún ipò Gómìnà ní ìpínlè Eko, tí a mò sí Babajide Sanwoolu àti akegbé rè tí òun a máa jé, Omòwé Obafemi Hamzat ní ìlú Èkó ní àná pàdé àwon gbajúgbajà àti àwon òsèré nlá nlá.
Won sòrò nípa ètò orò ajé to ìpínlè Èkó ní ìgbà ti won.Àwon òsèré bíi Yinka Quadri, Adebayo Salami (Oga Bello), Jide Kosoko àti béè béè lo.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti