Home / Art / Àṣà Oòduà / Ejò nlá kan (paramólè) tí won pa ní agbègbè mi láìpé ní àró yí.

Ejò nlá kan (paramólè) tí won pa ní agbègbè mi láìpé ní àró yí.

Ní àárò yí nígbà tí mo ti setán láti ma lo sí ibi isé ni mo pàdé àwon ògbéni yí, tí won n yo látàrí wípé won pa ejò, tí mo rò wípé paramólè ni, tí won sì ti gbèrò láti sè je .

Ó ti è ti pé tí mo ti fi ojú mi kòrókòró kan ejò nlá. Èrù bàmí ó sì yà mí lénu nígbà tí arákùnrin yí fi kó orùn, tí kò sì bèrù .
E gbó sé èyin le je irú ejò báyìí?emi kò le je o .

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti