Home / Art / Àṣà Oòduà / Ẹlẹ́wọ̀n 2600 ni ìjọba tú sílẹ̀ ní Nàìjíríà nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus

Ẹlẹ́wọ̀n 2600 ni ìjọba tú sílẹ̀ ní Nàìjíríà nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tú ẹlẹ́wọ́n tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjì sílẹ̀ ní ọgbà ẹ̀wọ̀n káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Aregbesọla ní Ìjọba gbé ìgbésẹ̀ náà láti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn Coronavirus ní Nàìjíríà.

Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà ni àwọn tí yóó jẹ àǹfààní ìtúsílẹ̀ yìí ni àwọn ẹni tó bá ti kọjá ọgọ́ta ọdún, àwọn aláìsàn , àwọn tó ní àrùn ọpọlọ àti àwọn tó sẹ ẹ̀sẹ̀ kéékèké.

Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Rauf Aregbesola ló kéde rẹ̀ ní ibi ayẹyẹ tí wọ́n ti ṣe ìtúsílẹ̀ náà.

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

seun kuti

NAH UNA KILL AM ? Seun Kuti Slams Public Celebration Of Buhari’s Death