Home / Art / Àṣà Oòduà / Eniyan Kan Ku ni Mushin Narin Awon Omo Egbe Onijagidijagan
One dies in Mushin gang war

Eniyan Kan Ku ni Mushin Narin Awon Omo Egbe Onijagidijagan

Rogbodiyan ti o be sile larin awon omo egbe onijagidijagan, Alamutu ati Alaka ni agbegbe kan ti a un pe ni Mushin ni ilu Eko
eyi ti o fa ijamba ti o mu emi eniyan kan lo si orun aaremabo, rogbodiyan na be sile ni ojo isimi, nigba ti won tian ina
fitila fun ikan ninu awon omo egbe Alamutu ti o ku nipa ijamba oko ayokele,  Olugbe kan ti oruko re unje Kayode salaye wipe, awon egbe mejeji ni won ma un papo lati ba awon eniyan ni ayika Mushi ati Shomolu ja Sugbon awon Alamutu so wipe awon Alaka ki fun won ni owo ni gbe ti won ba ti loja ti won si fun won ni owo, idi eyi ni o fa ti won si fi egbe won sile lati ma da se laye ti won,
Nigba ti wahala na be sile, opopolo awon eniyan ti won ko mowo mese ni won fi arapa yanayana. Abenugo egbe olopa ti ilu eko so wipe, iroyin ija na to won leti, won si yara lo si be lati lo petu si arin awon mejiji, eyi ti aalafia si ti joba ni be.

English Version
Continue reading after the page break

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti