Ìjo̩ba àpapò̩ kéde ‘June 12’ gé̩gé̩ bí o̩jó̩ ìsinmi lé̩nu isé̩ Lati odun to koja ni ijoba apapo ti yi ojo isejoba awa-ara-wa kuro ni ojo kokandinlogbon osu karun-un odun si ojo kejila osu kefa odun. Eyi waye lati fi se iranti Oloogbe Moshood Kashimaawo Abiola ti gbogbo aye gba pe ibo ojo kejila odun 1994 ni ibo ti o dara ju ni orileede yii. Won ni ibo naa ni ko ni ojoro ti o si lo ni irowo ati ...