Home / Art / Àṣà Oòduà / Gómìnà Arégbésolá fún àwon olùkó ní èbùn okò àti àwon èbùn míràn.

Gómìnà Arégbésolá fún àwon olùkó ní èbùn okò àti àwon èbùn míràn.

Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Rauf Aregbesola lo sí àjo àwon ilé-èkó àwon alákóbèrè pèlú àwon adarí míràn tí won péjú sìbè láti pín okò fún àwon òsìsé.
Kìí se okò níkan ni ó fún won o bí kò se wípé ó tún fún won àwon èbún míràn.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti