Home / News From Nigeria / Breaking News / Happy Ose Ifa Of Today….
ifa 100 percent honest
Cc- IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole

Happy Ose Ifa Of Today….

ifaOrunmila Jini kutu fere nire, Emini Ojumore lomo, Orunmila ni Ojumore lomo Olota nile ado…..
Orunmila Jini kutufere nire, Emini Ojumo Ire lomo, Orunmila ni Ojumo Ire lomo Erirun lode Owo….
Orunmila Jini kutu fere nire, Emi lojumo Ire lomo, Orunmila ni Ojumo Ire lomo peepe Lode Asin……
Orunmila Jini kutufere nire, Emi lojumo Ire lomo, Orunmila Lojumo Ire lomo Akapo toun Edu Alajogun…
Orunmila wani lati onilo Ojumo rere ni yio mamo Akapo toun, Yiodi Eni Ola, Yio di Olola….
OJUMO IRE NI YIO MO GBOGBO WA LONI OOOOO
[[[[[[[ASE]]]]]]]]

 

Orasakin Oraniyi Ifasesin Ajele

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Meet Venezuelan practitioners of the Yoruba Ifa tradition

Video: Meet Venezuelan practitioners of the Yoruba Ifa tradition

Venezuelan practitioners of the Yoruba Ifa tradition of Santeria are giving offerings to Oshun. Ifa is spreading. Originally practiced in Nigeria and other parts of West Africa, Ifa can now be found as far as Japan.