Home / Art / Àṣà Oòduà / Ifa kan lo soro ninu odu mimo re Oni.
opn ifa

Ifa kan lo soro ninu odu mimo re Oni.

Omi pakiti o be ona lori,Ona na pakiti o be omi lori,ipade omi oun ona parapo won je merin adifafun oyigiyigi tin sota omi,awa doyigiyigi ao ku mon oyigiyigi ota omi……..
Ao ni ku ni rewerewe taye n yeni o,oju ejo kifo oju gbogbo wa koni fo o,ope ki kanju ku ao ni kanju ku o,ire gbogbo ni soju owo ire a ma soju wa oooo……

—-ELABORU ELABOYE—-

Prince Aberefa Adesola

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ifagrithm

Ifagrithm: The Mathematics In Ifa (The Yoruba Divination System)