Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìgbéyàwó ìbílè ti Oludamilola Osinbajo àti Oluseun Bakare ní Aso Rock.

Ìgbéyàwó ìbílè ti Oludamilola Osinbajo àti Oluseun Bakare ní Aso Rock.

Ìgbéyàwó ìbílè ti Oludamilola Osinbajo àti Oluseun Bakare ní Aso Rock.

Èyí ni àwòrán láti òdò igbákejì Ààre, professor Yemi Osinbajo, omobìnrin rè Oludamilola Osinbajo níbi ìgbéyàwó ìbílè rè èyí tí ó wáyé ní ilé Ààre orílè èdè Nàíjíríà. Igbákejì Ààre, ìyàwó rè àti àwon àlejò míràn ló oé síbè.

Aya tí n bò lónà, Damilola ní ojó ketàdínlógún ní osù Erénà, 2018 tí yóò di aya Oluseun Bakare, Alagba ní ìjo Redeemed Christian Church of God àti omo Bola Shagaya tí ó jé sòwòsòwò àti gbajúgbajà…

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete