Home / Art / Àṣà Oòduà / Iná gbé arabìnrin kan tí ó jé akékòó ifáfitì ní ìjoba ìpínlè River (River state university). 
asa yoruba news

Iná gbé arabìnrin kan tí ó jé akékòó ifáfitì ní ìjoba ìpínlè River (River state university). 

Akékòó ifáfitì ní Ìjoba ìpínlè River kan tí a ò tíì mo eye to ó su ú ni Iná gbé ní ojó ìségun (Tuesday) ojó ketàlá osù kefà (June 13). A bá a tí ó subú lulè léègbé kan tí kò jìnà sí ilé-ìwé náà tí won sì gbé e dìgbàdìgbà lo sí ilé-ìwòsàn ilé-ìwé náà, kí ó tó di wípé Dókítà fi ìdí rè múlè wípé ó ti kú.

Gégé bí ojú tí ó ríi se so. Omobìrin náà ń gbìyànjú láti dá àgbàrá òjò kojá, nítorí òjò kan ti ń rò láti òwúrò ojó náà.

“Àgbàrá òjò tí ó fé dákojá  yí òpó Iná kan ti wó sí inú rè ní ojó ajé (Monday) ojó kejìlá  osù kefà (June 12).olóògbé kò sì mo èyí”.

Arí gbó wípé àwon aláse ilé-ìwé yìí  ti fi tó àwon olùmójútó (PHED) létí wípé òpó kan ti wó.

 

English Version
Continue after the page break

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti