Home / News From Nigeria / Breaking News / Iwure owuro ojo oni 17/07/2016
odu ifa

Iwure owuro ojo oni 17/07/2016

E maa wi tele mi :

*Edumare pese owo irorun fun mi.
*Edumare dakun faanu wa mi ri.
*Edumare ma fi mi daamu aye.
*Eleda a mi ma faye daamu-un mi.
*Ogun roju je roju mu koni je temi
*Egun aye ko ni gun mi(ase).
………………………..

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti