Home / News From Nigeria / Breaking News / Lakinni Ajakinni Ajinni…

Lakinni Ajakinni Ajinni…

Lakinni Ajakinni Ajinni, Oba ma pe mo pe o loruko, nigbati oju pon Alara, Alara pe o loruko, odi eni ajiki.
Lakinni Ajakinni Ajinni, Oba ma pe mo pe o loruko, nigbati oju pon Ajero, Ajero pe o loruko, odi eni ajikii.
Lakinni Ajakini Ajinni, Oba ma pe mo pe o loruko, nigbati oju pon Orangun Aga, Orangun Aga pe o loruko, odi eni ajiki.
Oju owo lo pon mi loni o, ni mo se pe o loruko, jeki owo jiiki mi,
Oju omo rere lo pon mi loni o, ni mo se pe o loruko, jeki omo rere jiiki mi,
Oju nkan mere mere ti omo enia nse nile aiye lo pon mi loni o, je ki nkan mere mere ti omo enia nse nile aiye jiiki mi,.
Ki Eledumare wa fi ire gbogbo jiiki wa o.

Ase.

Elaboru o, Elaboye!

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

1472 lagos

Is Oyo an Oppressor or a Protector? | How the Portuguese Arrival in Lagos in 1472. £P1.