Home / Art / Àṣà Oòduà / Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò darapò mó egbé APC.

Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò darapò mó egbé APC.

Olóyè Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò fi egbé alásìá, PDP (People Democratic Party)sílè lo dí egbé onígbálè APC (All Progressive Congress).
Ìròyìn jé kí á mò wípé ìgbésè Obanikoro lo sí egbé tuntun ti bèrè láti bi osù mélòó séyìn sùgbón won sèsè gbà á láyè gégé bi omo egbé ni .
Won sì ti ki káàbò gégé bi omo egbé APC (All Progressive Congress).

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

1472 lagos

Is Oyo an Oppressor or a Protector? | How the Portuguese Arrival in Lagos in 1472. £P1.