Home / Art / Àṣà Oòduà / Ninu Iroyin Owuro ose yii: Okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito ni Mowe, loro ba di gobe
iroyin

Ninu Iroyin Owuro ose yii: Okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito ni Mowe, loro ba di gobe

Ninu Iroyin Owuro ose yii: Okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito ni Mowe, loro ba di gobe

Iroyin Owuro ose yii tun ti gori igba. Iwe iroyin ti n gbona felifeli. Die ni yii ninu awon koko iroyin ose yii

* Ireti ati di minisita: Aregbesola re Oyinlola lepa

*Arekenge! Osinbajo ati aya re fife han nita gbangba

*Kayeefi! Omo tuntun gbe Bibeli waye ni Ila Orogun

*Ni Mowe, okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito

*Oba Deji Akure fi ibinu gbade lori oba Ibo

*Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu Ode

*Fayose kede nomba ero ibanisoro re fun awon eniyan ipinle Ekiti

*Abiyamo gbe omo re ta nitori owo

*Awon ota ko deyin leyin Ameachi

*Ayeye ojo ibi Alaafin Oyo: Oba Lamidi pe eni odun metadinlogorin

Ogorun naira pere ni Iroyin Owuro. E ri daju wi pe e beere lowo fendo yin. Aseti kii bojo, aseti kii boorun, aseti ko ni bayin laelae.

Ase

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

nigerian police

Họ́wù! Àgọ́ ọlọ́pàá ni wọ́n tí fọmọ odó lu èèyàn méjì pa

Họ́wù! Àgọ́ ọlọ́pàá n wọ́n tí fọmọ odó lu èèyàn méjì pa Ará kò níí tán nílé alárà láé láé. À bí kínni kí á tí wí pẹ̀lú bí èèyàn méjì ti kú lẹ́yìn tí ọlọ́pàá kan fi ọmọ odó lu ọ̀dọ́ mẹ́ta fún pé wọ́n jí adìẹ. Ẹnìkẹta, Abdulwahab Bello, nìkan ni ó yè. Ṣùgbọ́n, ó fi ara gba ọgbẹ́, tí egungun rẹ̀ sì kán, lẹ́yìn tí ọlọ́pàá náà lù wọ́n ní àgọ́ ọlọ́pàá kan ní Ìpínlẹ̀ Bauchi. Abdulwahab ...