Home / Art / Àṣà Oòduà / “Ó ye kí obìnrin náà ní ànfààní àti fé okùnrin Mérin” òdóbìnrin mùsùlùmí yí ló so béè.

“Ó ye kí obìnrin náà ní ànfààní àti fé okùnrin Mérin” òdóbìnrin mùsùlùmí yí ló so béè.

    9Ò n lò èro ayárabíàsà (Twitter) tí a mò sí Halima ni òpò ti takò látàrí wípé ó so wípé ó ye kí won gba obìnrin náà láyè kí won fé ju okùnrin kan lo.

Ní òtító olórun kò fi àyè gbà kí obìnrin fé ju okùnrin kan lò, ó sì wí “mé” fún okùnrin sùgbón ó fi “sùgbón” si tí òpò okùnrin kò sì mo nkan tí “sùgbón” náà túmò sí.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti