Home / Art / Àṣà Oòduà / Ogún-l’ógbòn àwon baba ńlá ìran yorùba l’ójé alágbára, lára won ni *Timi Àgbàlé olófà iná*.

Ogún-l’ógbòn àwon baba ńlá ìran yorùba l’ójé alágbára, lára won ni *Timi Àgbàlé olófà iná*.

Timi Àgbàlé, olóde tí ó sì jé jagunjagun tí Aláàfin rán lo sí ìlú Ede láti dáàbò bo àwon ènìyàn ibè.
Alágbára ènìyàn ni Timi jé , tí a sì mò ó sí *Timi Àgbàlé olófà-iná*,gégé bí ìtàn se so, ó jé okùnrin tí ofà rè má yo Iná.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti