Home / Art / Àṣà Oòduà / Ní Ojúmọ́ Ọjọ́ Àbámẹ́ta Tòní – #Kojoda #Yoruba #Orisa
Àbámẹ́ta

Ní Ojúmọ́ Ọjọ́ Àbámẹ́ta Tòní – #Kojoda #Yoruba #Orisa

Òsùn gbó ríró, kí o má dubúlẹ̀
Òòró gangan laa bósùn
Òsùn dé o Alàwòrò 
Ọlọ́run ọba ma jẹ kí gbogbo wa saarẹ

Mo sé ní ìwúre fun orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta tòní wípé àìsàn kéré tóbi aráyé kò ní fí se wá tọmọ tọmọ tebí tará
Ọlọ́run kò ní jẹ́ ka dùbúlẹ̀ àìsàn tọmọ tọmọ 
Gbogbo àìsàn arawa Olódùmarè yoo wòwá sàn 
kí ọ̀sẹ̀ yí tó parí

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

1472 lagos

Is Oyo an Oppressor or a Protector? | How the Portuguese Arrival in Lagos in 1472. £P1.