Home / Art / Àṣà Oòduà / #Opele- Ifa ni…
opele
Ọ̀pẹ̀lẹ̀

#Opele- Ifa ni…

Ifa ni:
Opele lo yo tan lo dakun de’le
A difa fun peregede tii se Yeye Ojumomo. Ojumo to mo wa loni ojumo ire ni Peregede!
Ifa iwo ni Yeye Ojumomo
Ojumo to mo wa loni ojumo Ajé ni Peregede
Ifa iwo ni Yeye Ojumomo
Ojumo to mo wa loni ojumo alafia ni Peregede
Ifa iwo ni Yeye Ojumomo
Ojumo to mo wa loni ojumo ayo ni Peregede
ifa iwo ni Yeye ojumo mo!
Aase!

 

Idowu Odeyemi

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

opele

Ifa Divination: Ọ̀pẹ̀lẹ̀