Home / Art / Àṣà Oòduà / *ORIN ORILE EDE NAIJIRIA NI EDE YORÙBÁ*
Nigeria Flag

*ORIN ORILE EDE NAIJIRIA NI EDE YORÙBÁ*

  1. ESE KINNI_
    Dìde Èyin Ará
    Waká jé ipe Nàijíríà
    K’à fife sin ‘lè wá
    Pel’ókun àt’sígbàgbó
    Kìse Àwon Àkoni wá,
    kò máse já s’ásán
    K’à sin t’òkan tará
    Ilé t’ómìnira,àt’àláfíà
    So d’òkan.

*ESE KEJI*
Olórun Elédàá
Tó ipa Ònà wa
F’ònà hàn asáajú
K’ódòó wa m’òtító
K’ódodo àt’ìfé pòsi
K’áyé won jé pípé
So wón d’eni gíga
K’álàfíà òhun ètó lè
Joba ní’lè wa.

*IJEJE*
Mo sè Ìlérí fún Orílè-Èdè mi Nàijíríà,
Láti jé olódodo, enití Ó see f’okàn tàn-án
Àti olótìtóó ènìyàn
Láti sìn ín pèlú gbogbo agbára mi,
Láti sa ipá mi gbogbo fún ìsòkan rè
Àti láti gbé e ga fún Iyì àt’Ògo rè.
Kí Olórun ràn mí l’ówó.

About Awoyemi Bamimore

One comment

  1. Orin na dun gidi gan. Mo feran re pupo

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti