Home / News From Nigeria / Breaking News / Pásítò̩ ká ìyàwó pè̩lú o̩kùnrin mìíràn lórí bé̩è̩dì rè̩
nabbed

Pásítò̩ ká ìyàwó pè̩lú o̩kùnrin mìíràn lórí bé̩è̩dì rè̩

Pásítò̩ ká ìyàwó pè̩lú o̩kùnrin mìíràn lórí bé̩è̩dì rè̩


Gbaju-gbaja Pastor ti gbogbo eniyan mo si Pasito Chriacus to je omo bibi ipinle Anambra amo ti o fi agbegbe Ikotun ni ilu Eko se ibujokoo ni eru Olorun tun ba pelu ohun toju re ri.


Okoowo karakata ni Pasito Chriacus n se tele ni ilu Ikotun ki o to di pe o ni Olorun pe oun lati sise fun Un.
O ni lati igba ti oun ti bere ise ojise yii ni iyawo oun ti bere ogun pe oun ko gbele mo, oun ko foju to omo ati bee bee lo.


Eyi ni iyawo naa si gun le pe ooto ni oko oun n so, ko ri aaye fun oun ati awon omo marun-un ti oun bi fun un mo lati igba to ti bere ise iranse naa.
Chinyere to je iyawo re ni eyi lo faa ti oun fi wa eni to maa mu ki inu oun dun ti awon si jo n sere.


Pasito ni awon ara adugbo ti n so oro yii ti pe pe iyawo oun n yan ale ti oun ni ko le sele si iyawo ojise Olorun. Afi bi emi Olorun se ni ki oun wale ni ojo kan ti iyawo oun ko lero, bi oun se ba okunrin miiran lori iyawo oun niyi ni ori beedi awon.


Pasito ni Satani to n gbe inu iru obinrin yii ni o mu ki oun lee danu lasiko naa ki o maa ba ba ise Olorun je lara oun.

Láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

yoruba

Can we speak Yoruba language without code mixing? is it important?