Peter Okoye ti gba Emem Ema ‘Vzhun’ gégé alákoso rè tuntum.
Olórin, peter Okoye tí a mò sí Mr.P tí ó ti fi èkejì rè sílè, Paul Okoye àti alákoso won, Jude Okoye ti gba alákoso tuntun.
Ó sì ti pín àwòrán náà sí orí èro ayélujára (Instagram). Kí èsù má da àrin won rú.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

