These are photographs of SOME of previous Petroleum Minister Diezani Alisson-Madueke’s properties in the UK. Photos were supplied by Jeremy Weate who made a go at searching for one however revealed more than he haggled for…..
Foto tuntun Diezani Allison-Madueke ni yii, minisita fun epo robi nigba kan ri, eni ti won fesun jegudujera kan niluu London. Won ni ara madaamu naa ko ya rara. Joojumo si ni ipo ilera re n buru sii. Arabirin naa niidi adura bayii, ki Olorun alaanu ba wa da alaafia pada si lara. Ase ! Olayemioniroyin.com