Home / Art / Àṣà Oòduà / SANGO, kABIYESI O!!! LALU OBA KOSO ORIKI SANGO.

SANGO, kABIYESI O!!! LALU OBA KOSO ORIKI SANGO.

Olúkòso!

Atu wón ka níbi wón gbé ‘ndáná iró.

A lé Babaláwo máa dúró kó Ifá,

À ti lójò àti lérùn,

Kò séni tí Sàngó kò lè pa.

À f’eni tí kogílá kolù,

À f’eni tí Esù ‘nse,

Ló máa fé kolù Esù.

Ló máa fé kolù Sàngó.

À ‘feni tí Sàngó yío pa.

Ló má ko lu Sàngó.

Olúkòso oko Obà, Oya, Osun.

Oba kòso oko mi,

Bálé mi ògiri gbèdu.

‘N ko je kolù e lónà òdi o.

Asé!

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti