Gbajúgbajà ò n lò èro ayélujára tí a mò sí Toke Makinwa tí gbé ògo tí olórun fún hàn, nígbà tí ó gbé àwòrán ìgbà tí ó wo aso ìwè sí orí èro ayélujára tí ó n jé Ínsítágírámù .
Àwòrán tí ó gbòde yí ni ó yà ní èbá òkun ní ìlú Èkó. Toke tí won so wípé bí ó bá yá ti è yóo ju ti Kim Kardashian lo.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

