Home / Art / Àṣà Oòduà / Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá.

Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá.

Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá.
Gbajúgbajà àti ìlú mòóká òsèré tí a mò sí ìyá ìjo, Tonto Dikeh, ti gbe lo sí orí èro ayélujára Ínsítágírámú láti jé kí ámò wípé nse ni ó dàbí eni wípé òun máa se isé abe ojú míràn.
Tí a bá rántí dáadáa bíi osù méwàá séyìn ni ó so wípé òun fé se isé abe láìpé sì ni èróngbà rè wá sí ìmúse.
Ó gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín wípé òun náa òpòlopò mílíònú náírà láti fi se isé abe náà . léyìn osú díè tí ó ti fi èyi se oge tán ni ó bá túngbèrò láti se òmìràn fún ìgbà èkejì.
Arewà tí ó tún jé ìyá omo kan ní ojo mérìnlá osú kokànlá odún yí (14/11/2018). Ojó rù, pín àwòrán òun pèlú Dr. Rasheed Ayobami Aranmolate nígbà tí ó bérè wípé se Oliver Twist ni.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti