Home / Search Results for: Imo (page 6)

Search Results for: Imo

Ìsìnkú àwon tí won kú níbi ìjàmbá okò tí ó selè láìpé ní ìpínlè Imo.

Gégé bí Holychidi Ojlkorie, ìgbákejì olùgba oko àti aya n’ímòràn ti ìjoba ní ìpínlè Imo télè, òpò ènìyàn bí ogbòn ni won kú níbi ìjàmbá burúkú tí ó selè láìpé láàrin glokò epo petiróòlù àti okò èrò elérò méjìdínlógún (18) ...

Read More »

Banky W àti òré tímótímó tí ó rè le lo gba ìyàwó rè ( Adesua Etomi), Tunde Demuren .

Banky W àti òré tímótímó tí ó rè le lo gba ìyàwó rè ( Adesua Etomi), Tunde Demuren . Banky W àti òré rè tímótímó fún ìgbéyàwó alárédè rè, Tunde Demuren ni won Jo ya àwòrán papò níbi ìgbéyàwó alárinrin ni ...

Read More »

Okò tí ó gbé epo petiírólù àti okò èrò ni ó kolu ara won ní Orlu Imo, ogbòn èèyàn ni ó kú.

Ìjàmbá nlá ni ó selè ní orí afárá (bridge) tí ó gbajúgbajà ní Njaba lónà Umuaka – Okwudor ní ìpínlè Imo. Gégé bí ìròyìn se so okò epo petiírólù àti ti gáàsì tí ó kolu bóòsì elérò méjìdínlógún ní Orlu, ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tí àwon àgùnbánirò méjì yí yà ní ìpínlè Imo, láti e n lé (Hello) di e pèlé(Hi) títí di ìgbéyàwó.

Ìgbéyàwó eka-èkó (departmental weeding) ni, ìgbéyàwó àgùnbánirò ni tí ó bèrè láti e n lé di e pèlé, tí won wá di orè tímótímó eka-èkó tí won sì padà di olólùlé eka-èkó báyìí ó ti di ìgbéyàwó eka-èkó. Ihekuna Ann ...

Read More »

Patience Jonathan níbi ayeye ìgbéyàwó omobìnrin asojú ilé ìgbìmò asòfin, Sekibo.

     Aya Ààre télè, Dame Patience Jonathan yo ní àrà òtò láti yé adojú ilé ìgbìmò asòfin Thompson Sekibo bí ó se no àkóbí rè lówó níbi ìgbéyàwó yí ní ìlú Ogun.

Read More »

Ère Nana Akufo- Addo ni Rochas Okorocha fé sín ní Imo.

   Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha ti se tán láti sín ère ààre Nana Addo ti Ghana ní Owerri nígbà tí ó ti sí ère ti ààre Ellen Sirleaf ti Laberia àti Zuma ti South Africa . Ère náà ti ...

Read More »

Isé abe tí ó bùáyà, Hushpuppi káàbámò lábé abe , ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.

   Léyìn isé abe ; Hushpuppi káàbámò, ó sì gba àwon èèyàn n’ímòràn.

Read More »

D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin Dino Melaye .

   D’banj lo kí asojú ilé ìgbìmò asòfin ni ó pín àwòrán yí “koko master náà ni”.

Read More »

Won gbìmò láti da ilé mi wó, Dino Melaye se béè fún Yahaya Bello.

   Asojú ilé ìgbìmò asòfin Melaye ti tako Gómìnà ìpínlè Kogi Yahaya Bello tí ó gbèrò láti wó ilé rè ní ìpínlè Kogi. E kàá dáadáa.

Read More »

Ààre Buhari lo rí àwon omo egbé CAN ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.

   Ààre Muhammadu Buhari ti lo rí àwon omo egbé Christian Association of Nigeria (CAN ) ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb