Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

The Coronation of The 21st Olu of Warri Event

Live Event Video: The Coronation of The 21st Olu of Warri

The Coronation of The 21st Olu of Warri Event

Read More »
ifa oodua

Aku ójúmó Toni 🌴

Asiku ose ifa osun egbe Ori Toni 🌴Ifa ni ibo legbe ibo lawure adifa fun orunmila baba yio so akapo re di oba ebo lawo nikose inje enitoba fe laje komo setutu ibo legbe ibo lawure.enitoba fe laya komo setutu ...

Read More »

The 21st Olu Of Warri Coronation

Join us on the 21st of August as we celebrate the coronation of the 21st Olu of Warri kingdom.

Read More »

Ọdún orò gbìnà yá, ìdájí ní àwọn olórò yóò fi máa yíde ìlú níṣẹ̀yin

Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn ...

Read More »
Adúmáadán Àjèjé

Adúmáadán Àjèjé

Ẹmu daada ní ń bẹ nínú aháÒgùrọ̀ àtàtà ní ń bẹ nílẹ̀ akèrèǹgbèỌtí ò dá, àlejò ò lọ!Ẹni ọtí kìí tí AdúmáadánAdúmáadán Àjèjémá gbádùn ara rẹ lọ! ‘Òògùn ibà ni, òògùn ibà ni,’Bí eré, bí eré ìyálé ilé mútí yó!Ẹmu ...

Read More »

Fayose kò mo̩ bò̩ò̩lì àti àgbàdo je̩ tó mi,àmó̩… – Fayemi

Gomina ipinle Ekiti, Dr Kayode Fayemi lo n salaye yii nibi eto ori telifison Kan ti arabinrin Morayo Afolabi n dari re.Leyin ti gomina dahun orisiirisii ibeere ni arabinrin naa wa tun beere asepo to wa laarin oun ati gomina ...

Read More »

Ti o ba ka iwe yii fi ara e han

Read More »
owe

E fun mi ni owe to ni Ile(house) ninu ?

Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu. E seun.

Read More »
Odu Ifa

Owonrisogbe – Ifá Naa Ki Bayi Wipe: Biijo biijo…

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku orire osu Ògún tuntun to bawa layo ati alaafia, osu naa yio sanwa sowo, somo, sile kiko, moto rira, ire oko/aya ati aiku baale oro yio ...

Read More »

Eríwo Yà! Eríwo Yà!! Eríwo Yà!!!

Ṣí Gbogbo Babaláwo àti Oníṣẹ̀ṣe lápapọ̀, Ní òní yìí (ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, oṣù kejèe 2019) ni ìgbẹ́jọ́ tó bẹ̀rẹ̀ ní ìtàdògún tó kọjá lọ (Tuesday, 9th of July 2019) parí (tí ìdájọ́ sì wáyé pẹ̀lú) lórí ẹ̀sùn oyún síṣẹ́ fún ọ̀dọ́mọbìnrin tó ...

Read More »