Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 20)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Òdókùnrin kan ní àwon olópàá yin ìbon pa nígbà tí won fé parí ìjà ní Ajegunle.

Òdókùnrin kan tí a gbó wípé ó jé omo ogún odún ni a gbó wípé won fi èsùn kàn àwon olópàá Látàrí ìbon tí won yìn pa Òdókùnrin yí, nígbà tí won ń parí ìjà lówó láàrin àwon ìkò ológun ...

Read More »

Paul Okoye níbi tí ó ti ń bá àwon ìbejì rè Nadia àti Nathan seré .

Paul Okoye tí a mò sí Rude boy ni ó pín àwòrán tí ó rewà yí nígbà tí ó ń lo àsìkò pàtàkì pèlú àwon ìbejì rè Nadia àti Nathan seré èyí tí ó pín sí orí èro ayélujára (instagram)..

Read More »

Kemi Olunloyo so báyìí wípé! Àwòkóse burúkú gbáà ni Linda Ikeji àtiwípé òun ni àwòkóse there.

Kemi Olunloyo so báyìí wípé! Àwòkóse burúkú gbáà ni Linda Ikeji àtiwípé òun ni àwòkóse rere.OK olunloyo so òpòlopò àsírí nípa oyún inú Linda Ikeji àti nípa ara rè pàápàá. Àtiwípé Linda Ikeji ti kó bá òpòlopò òdóbínrin.

Read More »

Sùúrù lógbà.

Ìsé kìí se ohun àmúseré Ìyà kìí se ohun àmúsàwàdà Ebi ń pamí kìí mérìń p’ani Sebí ebi kìí w’onú Kí òrò míràn wòó Ojú tí ń kúkú pón isin Kìí se àpón ku Bí kòse àpónlà Bówù kópé títí ...

Read More »

A o ni ri ogun aisan

A o ni r’ogun aisan! Ifa ni: Pere ni tewe iyeye, aloye ni ti peregun; Piri l’eye olongo n ji; A kii b’okunrun eye lori ite; Gege lowu alantakun n fuye; Ota kii ku, ota kii run; Koko lara ota ...

Read More »

Àfi kí á ma dúpé.

Àfi kí á ma dúpé . Ìwo tí o wà láyé Tí ò ń jeun àsìkò Tí o tún ń wo aso àsìkò Ó tó kí olúwa rè sopé Olúwa tún wá ba o se é Ó tún fún o ...

Read More »
yorubia

ORIKI ILORIN Ilorin afonja.

ORIKI ILORIN Ilorin afonja enudunjuyo Ilu to jinna s’ina To sunmon alujana bi aresepa Ilu tobi to yen,won o leegun rara Esin l’egungun ile baba won Akewugberu ni won A s’adura gbore Aji fi kalamu da won lekun arise kondu ...

Read More »
Yoruba

ORÍKÌ OFA

Otunba Ikanni: Iyeru okin olofa mojo, Omo olalomi, omo a basu Jo o ko Omo la a re, bu u re, Okan o gbodo jukan, Bokan bajukan Nile olofa mojo, Ogun Oba ni i kowon ni roro, IJA kan IJA ...

Read More »

Oríkì Òsun

Òsun sègèsé olórìyà iyùn Awede kí ó tó we’mo Òsun eléyinjú àánú Igbómolè obìnrin Òsaàyò m’olè Òmómó t’enu m’olè Ayaba bìnrin òtòrò èfòn n’ílé ìyá olúgbón Won kò gbodò m’awo Ìran Arèsà Won kò gbodò m’orò Olúwa mi ló m’orò ...

Read More »

SANGO, kABIYESI O!!! LALU OBA KOSO ORIKI SANGO.

Olúkòso! Atu wón ka níbi wón gbé ‘ndáná iró. A lé Babaláwo máa dúró kó Ifá, À ti lójò àti lérùn, Kò séni tí Sàngó kò lè pa. À f’eni tí kogílá kolù, À f’eni tí Esù ‘nse, Ló máa ...

Read More »