Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 16)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Arábìnrin tí kò ju omo odún métàdínlógún (23) lo ta omo rè òsé méfà tí ó sí fi owó rè ra èro ìbánisòrò ní ìpínlè Edo.

Owó àwon agbófinrín ti te arábìnrin kan ní ìpínlè Edo tí ó jé ìyá omo méjì , Miracle Johnson, fún títa omo rè omo òsè méfà tí ó sì di owó náà ra èro ìbánisòrò fún ara rè. Gégé bí ...

Read More »

Ajimobi àti Yinka Ayefele pàdé níbi ayeye Àádòrún odún (90) ojó-ìbí Olúbàdàn.

Ajimobi àti Yinka Ayefele pàdé níbi ayeye Àádòrún odún (90) ojó-ìbí Olúbàdàn. Ìyàlénu ñlá gbáà ni ayeye Àádòrún ojó-ìbí olúbàdàn ti ilè ìbàdàn tí a mò sí Oba Saliu Akanmu Adetunji ní ojó Àìkú. Gómìnà ìjoba ìpínlè Oyo Abiola Ajimobi ...

Read More »

Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà .

Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà . Sineto Musiliu Obanikoro tí ó jé adarí àwon olúdábòòbò ti orílè èdè Nìjíríà télè ti lo kí baba wa Oònirìsà tí a mò si àrólé odùduwà ní ìlú ilé-ifè ní ojó mélòó ...

Read More »

Ìròyìn burúkú gbáà ni ó jé nígbà tí a gbó wípé baba omo Bisola tí ó jé òkan lára àwon omo ilé BBNaija télè kú.

Ìròyìn burúkú gbáà ni ó jé nígbà tí a gbó wípé baba omo Bisola tí ó jé òkan lára àwon omo ilé BBNaija télè kú. Ará ilé àti lára àwon tí ó figa gbága ní BBNaija rí ni Bisola Aiyeola ...

Read More »

Ènìyàn tí ó n gbé inú èkú láti ojó yìí tí a kò mò tí ó n jé lágbájá, àwòrán è rèé.

Okùnrin kan tí ó n gbé inú èkú fohún bí egúngún tí a mò sí lágbájá ni àwòrán hàn ní ìsàlé yí fún ànfààní àwa tí a kò da mò. Gbajúgbajà olórin a kó ni l’ógbón ni Lágbájá àwòrán rè ...

Read More »

Favour Iwueze ti Destined kids ti setán láti se ìyàwó.

Omo kékeré àná náà ti dàgbà, àdúrà wa ni wípé kí olórun má pa omo fún olómo. Favour Iwueze ìkan lára àwon omo kékeré ìgbàyan ti setán láti se ìgbéyàwó, kí ire ayò náà kárí.

Read More »

Oòni ti ìlú ilé-ifè darapò mó àwon mùsùlúmí ilé-ifè láti kírun ní ojó odún iléyà tí a mò sí Eid-el kabir.

Gégé bí a se mò wípé àwon omo léyìn músùlùmí sèsè se àsekágbá odún won ní léyìn tí won ti gba ààwè séyìn léyìn bí osù mejì àti òsè mélòó sèyìn. Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti darapò mó àwon músúlúmi ...

Read More »

Arákùnrin kan ni ó na ìyàwó rè, tí ó sì ba àwò ara ré je.

Arákùnrin kan ni a gbó wípé ó na ìyàwó rè tí ó sì dá àpá si lára, ládúrú bí won ti se n kó wa ní èkó lórí bí a se le gbé lókoláya tó. Bí ó tilè jé wípé ...

Read More »

Odún ìsèsi àgbáyé

Ogúnjó osù kejo (20/8) odoodún ni odún ìsèsi màa ń wáyé káàkiri àgbáyé. Ìlú kòòkan ni ó sì máa ń se odún náà sùgbón àwon ìpínlè Kan wà tí won máa ń se é papò bí ìpínlè Osun. Àjòdún odún ...

Read More »

Èèmò! Nígbà tí Gómìnà ìjòba ìpínlè Oyo wó ilé ìròyìn Yinka Ayefele ní ìlú Ibadan. Èyí kìí se àheso rárá, béè ní Gómìnà ìpínlè Oyo kò bá Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yinka Ayefele se eré rárá.

Ní òwúrò ànà tí se ojó Àìkú ní ariwo ta ní ìlú Ibadan ní ìpínlè Oyo nígbà tí ijoba ìpínlè náà pàse kí won wó ilé-isé ìròyìn ti Yinka Ayefele tí a mò sí Fresh Fm tí ó wà ní ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb