Minisita fun eto ilera, Ojogbon Isaac Adewole, ti se idaniloju alaye wi pe, efon abami ti n sokunfa kokoro Zika ti ko gboogun ti wa ni Naijiria. Bakan naa lo si ro awon eniyan lati se ohun gbogbo ni ikapa ...
Read More »Bayii ni a se le se iwosan fun eni to ni kokoro inu eje
Awon ohun elo ti a gbodo wa ni yii: 1 Omi osan wewe igo kan tabi oti igo kan tabi omi grape igo kan 2 Capsule red & yellow eyo mewaa (10 pieces) 3 Ewe taba ti won ti ...
Read More »Ewu to wa ninu foonu lilo ati pataki ilera wa
Opolopo wa ni a n lo foonu ni aye ode oni, sugbon ti a kosi mo awon ewu keekeke to ro mo o eleyii to le se ipalara fun ago ara wa. E je ka ri daju wi pe a ...
Read More »Iwosan ogbe inu
Awon nnkan won yii lo maa n se okunfa ogbe inu; ki eniyan maa fi ebi pa ara re nigba gbogbo, jije ounje gbigbona ati iyo pupo ninu ounje ati bee bee lo. Bi a se maa se iwosan naa ...
Read More »E jowo eyin, abiyamo, e dakun e gba wa ni imoran ..
OOOOOOO Oro naa ti di lbanuje ati edun okan fun molebi mi, e dakun e gba mi ooooo. Mo je Omo odun metadinlogbon (27 years) Taiwo. . . . . . ni Oruko mi, Okunrin ni mi, bakan naa ni ...
Read More »Awon agbejoro tuntum ti ogbeni saraki sese GBA ni yi o
Ejowo kini oruko won ?
Read More »Sisi ologe elo ni Suru ooo
Se Eledumare to da IDI yin bi o se mon IDI kaluku yin se ko se da ni in? Awon kan wa sese ma lo ogun abi abere. Se ni tori iranu yi na E wo won oooo. Awon kan ...
Read More »Awise Awo Agbaye Wande Abimbola
Eyin ojogbon eniyan, kini itumo awon oro won yii ?
Enikan lo lo ki ore re,ko si ba ore re nile, sugbon o ba okan ninu awon omo ore re nile. Oni baba re n ko? Omo naa ni:”Baba mi lo so okun (rope) aye ti o fe ja” Iya ...
Read More »Enikan lo lo ki ore re,ko si ba ore re nile, sugbon o ba okan ninu awon omo ore re nile. Oni baba re n ko? Omo naa ni:”Baba mi lo so okun (rope) aye ti o fe ja” Iya ...
Read More »