Moki gbogbo apapo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi ooo Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (Ilosiwaju ishese lo jemi lo gun ooo) EJOWO OO E NPE MI SI AKIYESI Oruko mi ni iyin oluwa moje enikan ...
Read More »An amazing piece of original art…
We are powerful, the words we speak carry power, the thoughts we entertain carry power, day dreaming is powerful. No more negative self talk aloud or in your head. You are an amazing piece of original art and you deserve ...
Read More »Photos From Olojo Festival
Prayer ‘s Been Done By The Isoro Traditional Council Of Elders Ile-ife, Led By Oba Farotimi Faloba (Obadio) Towards Ilagun ….ogun Lanire Ka Sodun Hi,ka Semirin Ooo,ki Le Gun ,ko Na Jooooo…. Kade Pelori Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Oonirisa)…kin Ile-ife ...
Read More »Aki Ijo Kinnihun Orunmila
(Atorieni Tikosun wonSe) TI ILU IBADAN LAPAPO OOO Aki gbogbo ojogbon awo mimo lapapo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi oo Wipe :- (KINNIHUN ORUNMILA O) (ilosiwaju ishese lo jemi lo gun o) Aki gbogbo apapo ojogbon awo mimo ...
Read More »Iwure Ojo Aje 3/10/2016
Ekaro oo se dara dara laji lowuro eni o gege bi emi na se ji oo toba ribee ejekia dupe lowo olodumare kiafi okan kan dupe lowo eleda wa ejekia bo si iwaju oke ipori wa pelu obi tabi eyi ...
Read More »Olojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Princess Oluwakemi Morenikeji Idowu ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re ...
Read More »Odu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe..
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Eku ojo meta o, Ogun lakaye yio bawa segun awon ota wa yio si lana ire gbogbo funwa loni ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Irete Osa kubu irete Osa kebe, irete ...
Read More »Ayeye Ojoibi Toni: Babami Oloye Olatbosun Oladapo
Ododun larorogbo Ododun lari awusa Ododun lati mo obi lori ate Ododun ni sapo nruwe Ododun ni peregun yio Ododun leo ma bee ninu ola ati Alaafia Alekun ogbon Alekun Oye Alekun IMO Alekun emi gigun Alekun Alaafia Oju asa ...
Read More »Ori mi segbe leyin mi ooo..
Ori eni lawure eni ni, Ori mi segbe leyin mi ooo. Ori a gbe wa o.Ase oo
Read More »Eniyan ku l’aye ara orun o sunkun
A soul is lost on earth but the dwellers of heaven shed no tears. The news of the death of Oloye Awopetu Idowu Omilola, Awise of Ijesa land was shocking to me. Ifa and Orisa community has lost another proficient ...
Read More »