Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 63)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

ewe okan

Ewe Yi Je Òkan Lara Awon Ewe Ifa To Dara Pupo

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, emin wa yio se pupo re laye ase. Laaro yi mofe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi lati inu odu ...

Read More »
ewe atitte ewe itare

Atitare/Itare: Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA

Aku ise ana o oni a sanwa o, aanu olorun Olodumare koni fiwa sile loni o ase. Laaro yi mofe ki e mo Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA, ati iwulo e ti o se ...

Read More »
ewe

Kini oruko ewe yi ?

Ejo kini oruko ewe yi

Read More »
ewe karaleye

Kereyale / Yale – Iwulo Ewe To Wa Ninu Aworan Yi

  Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a san wa sire gbogbo, bi odun yi se ntan lo akoni fi aisan pari re lase eledumare ase. Laaro yi mo fe ki a mo iwulo ewe ...

Read More »
ase

Bi Ere BI Awada Oorun Odun 2016 n lo Ibi Ati Wo….

Ni iru akoko yi opo ile ise nla nla ni won ngbaradi ati se akosile asekagba ise iriju won fun odun ti nlo sopin yin… Beeni opo osise ile ise wonyi ti a ti fun ni gbedeke nibi ise won ...

Read More »
odo iwoyi

Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ...

Read More »
ona

A té o náá…

A té o náá. Hee, a té o náá. Kí o tún ara e té o. Awo kì nlé ikún. Awo kì nlé ejò o. A té o náá kí o tún ara e té. Awo kì nsúré gun igi ...

Read More »
ewe

Ejo kini oruko ewe yi

Read More »
ewe alukerese

Orunmila ni awure emi naa moni awure

  Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku isimi opin ose adura wa yio gba o, ori buruku koni je tiwa o ase. Laaro yi mo nfe ki a mo iwulo ewe yi ...

Read More »

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb