Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 81)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Foto: Egbo tani eni to joko yi

Tani eni to joko yi

Read More »
ogogo

Arewa Asa Toni: 17-04-2016 Ogbeni/Alaji Taiwo Hassan (Ogogo)

Arewa asa wa toni ni Alhaji Taiwo Hassan, abi won ni Ilaro ni odun 1959, baba tobi won ibeji ni, baba tobi baba won ibeji ni, emerin ototo ni won ti bi ibeji ninu ile won,  Won losi ile-we alakobere ...

Read More »
opon ifa ade

Iwure Owuro Toni: 17-04-­2016

E MAA WI TELE MI : …… *Adun, ayo, idunnu ni temi titi aye *Ire owo, ire omo, ire aiku ni temi. *Apari inu mi ko ni ba tode mi je. *Orisun ayo mi ko ni gbe. *Ise mi ko ...

Read More »
odo

Odo Iwoyi !

A ki gbogbo wa ku ise oni, a si ki wa ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E dakun e wa nkan fidi le abi ki e fi idi le nkan, ki a ...

Read More »
olobe

Olobe Lo Loko Soko-Yokoto

Eto Olobe lo loko soko-yokoto ni o gori afefe bayii,,,,,, Adupe lowo olorun fun abo re lori wa, oba ti o pawa mo titi Di ojo oni, a dagbere ni ijejo, atun dupe wipe eledumare ka wa ye loni. Lori ...

Read More »
asa yoruba

Ayo Ab’ara Bintin

Ope ni fun Olorun nitori ti o seun ti anu Re duro laelae. Mo layo lati so fun wa wipe Eledua fi Omobinrin lantalanta da ebi kan pataki ninu ilu yi lola. Tii se ebi Olori AJOKE GOLD OLUWAKEMI ti ...

Read More »
Ngozi Nwosu

Ngozi Nwosu lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Ogulutu Oro Toni

si gbogbo okunrin hummmmm moseba gbogbo obinrin ooooooo………eyi ni oruko meta ti OLOHUN so wipe awon OBINRIN nje ti gbogbo OKUNRIN SI GBODO MO,,, Akoko:AWAWU Ekeji: ONIGBAGBE ENIYAN Eketa: ONIFENU # wo ore wa majeki ohun ti obinrin re tabi ...

Read More »
oro

Eba Wa Da Si Oro Yii ooo

Eyin Okurin Se ele gba wipe ki Iyawo yin je oga yin ni ibi ise ?

Read More »

Iroyin Ere Idaraya Lerefee (02-04-2016)

Ajo to n mojuto ‪#‎LEAGUE‬ awon obinrin nile wa “NWFL kede ola ojo keji osu kerin gege bi ojo ti idije boolu LEAGUE obinrin fun saa tuntun yoo gberaso kaakiri ile wa. ……….. Emi ati awon agbaboolu mi nlo si ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb