Orisiirisii ona ati idi pataki ni awon eniyan fi n yan ore tuntun. Awon kan fe alajoso, awon kan fe alabaro, awon kan si n fe eni ti won yoo jo maa takuroso lasan. Eyiowu ko je, ore dun ti ...
Read More »
admin Comments Off on E pade awon ore yin nibi
Orisiirisii ona ati idi pataki ni awon eniyan fi n yan ore tuntun. Awon kan fe alajoso, awon kan fe alabaro, awon kan si n fe eni ti won yoo jo maa takuroso lasan. Eyiowu ko je, ore dun ti ...
Read More »admin Comments Off on Kini ero yin nipa awon obirin to ga fiofio?
Mo mo wi pe awon obirin maa n fe lati fe awon okunrin to ba ga. Sugbon mi o mo boya bakan naa lori pelu awon okunrin nipa fiferan awon obirin to ga fiofio. Se kii se wi pe giga ...
Read More »admin Comments Off on Odun Iwude Ijesa: Gbogbo aye pejo saafin Owa Obokun
Ese ko gbero lojo Satide to koja yii niluu Ilesa nibi ti tonile talejo ti gbe pejo lati sodun Iwude Ijesa laafin Owa Obokun Adimula ti ile Ijesa, Oba Gabriel Adekunle Aromolaran. Gege bi a se gbo, ayeye odun Iwude ...
Read More »admin Comments Off on Odun 2016 yoo dun bi oyin: E ku odun tuntun
E ku odun tuntun. Odun ayo ati igbega ni yoo je fun gbogbo wa. Ase. Odun 2016 yoo dun bi oyin. Bee ni. E je ki eleyii je ero yin. Kosi tun maa jeyo ninu awon oro enu yin nigba ...
Read More »admin Comments Off on Igbeyawo omo Adewale Ayuba fakiki
Idunnu obi ni ki omo o yan ko si yanju. Omo taa to, to si duro gbeko ni i pada di omo gidi lowo awon obi re. Eyi ni a le pe ni itan Tiwalade Ayuba lowo baba re. Ayo ...
Read More »admin Comments Off on Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko
Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye latari ojo alagbara kan to si lule to si bere si ni se ...
Read More »admin Comments Off on Oserebirin wo leyii, Se e damo bi??
admin Comments Off on E wo ohun ti enikan so nipa ile epo Bovas to wa niluu Ibadan
Awon arije ni madaru, ika, odaju, ole, wobia, wonbiliki le po ni Naijiria loooto, sugbon awon eniyan rere ko ti tan lawujo wa. Okan ninu won ni alase ile epo Bovas to kale silu Ibadan. Bakan naa ni awon eniyan ...
Read More »admin Comments Off on Ijamba oko niluu Eko lojo odun keresimesi
Ti e ba muti, e ma wako; ti e ba wako, e ma muti. Okunrin kan lo koja lo sorun lojo odun keresimesi to koja yii ni akoko ti gbogbo eniyan n yo ayo iwasaye Jesu olugbala araye. Ijamba oko ...
Read More »admin Comments Off on Owo ti te Jaguda, Mohammed Isah to lu komisanna olopaa meji ni jibiti
Sebi ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo awon olopaa ilu Eko ti te omo gambari onijibiti kan ti oruko re n je Mohammed Isah, to lu komisanna ipinle Ondo ati Anambra ni jibiti. Omokunrin onijibiti naa ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more