Ile ejo ti ran Jimoh lewon leyin to fi ehin ja ori oyan asewo niluu Ibadan Orisun Oniroyin: Twitter Ile ejo Majisireeti ti n jokoo niluu Ibadan ti ran Ogbeni Sunday Jimoh lewon bayii leyin igba to fi ehin ja ...
Read More »Won je David Mark, Amaechi ati Fasola lenu bi obi abata
Orisun Oniroyin Twitter Won je David Mark, Amaechi ati Fasola lenu bi obi abata *Didake David Mark n ko awon eniyan lominu *Asa tuntun ti won da: “Mi o gba riba ri laye mi” – Amaechi “Gege bi gomina, mi ...
Read More »Ewi Awon Omode: E Ma Ya Baseje
Ewi: E ma ya baseje Eyin ewe iwoyii, e wa teti si agogo ogbon E ma ya baseje Baseje ti n bale je ni won pe larungun Arungun ni eni ti n ba ohun ti won fowo se je ...
Read More »Itan fun awon omode: Kinihun ololaaju ati eku inu igbo
Orisun Kinihun ololaaju ati e ku inu igbo Itan ti a fe gbe yewo lonii ni itan Kinihun ololaaju ati eku inu igbo. Gbogbo wa la mo wi pe kinihun loba eranko. Oun naa si ni eranko to lagbara ju ...
Read More »Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba
Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba Ni abala mooko-mooka ose yii, akoto ede Yoruba ni a maa gbe yewo. Akoto je ona ti n gba ko ede Yoruba sile laye ode-oni. Eleyii to yato si ti aye atijo. Aye Atijo Aye ...
Read More »Awon omo onimoto da gobe sile ni ipinle Ondo
Orisun Awon omo egbe onimoto NURTW eka ti ijoba ibile Owo to kale si ipinle Ondo buta sira won loju lojo Isegun to koja yii. Awon iko meji kan ti won je ti egbe NURTW la gbo wi pe won ...
Read More »Nje ohun to buru wa ninu ara bibo?
Nje ohun to buru wa ninu ara bibo? Idahun awon eniyan wa ninu linki isale yii: https://www.facebook.com/photo.php?fbid=904657846286766&set=gm.1070531176331524&type=3
Read More »Onka ede Yoruba 100 – 20,000
Orisun Onka ede Yoruba 100-Ọgọrun 110- Adọfa, àádọ́fà 120- Ọgọfa 130- Aadoje 140- Ogoje 150- Adọjọ, àádọ́jọ 160-Ọgọjọ 170-Adọsan, àádọ́sán 180- Ọgọsan 190-Mẹwadinigba 200-Igba E tesiwaju ni isale lẹhin iwe Bireki yii (Continue after the page break bellow)
Read More »Ki lo sele si Taiwo leyin iku Kehinde Osuolale (Ibeji Oran)?
Leyin odun kan ti Kehinde Osuolale dagbere faye, iroyin mi-in tun ti kan wa wi pe ikeji re, Taiwo naa ti lo ba ikeji re lajule orun. Ohun ti a gbo ni wi pe ilu Abuja ni Taiwo ku si. ...
Read More »Yoruba Customs & Beliefs Pertaining to Ojo Isegun (Tuesday) in relation to your Star
Source In yoruba culture and spirituality it is believed that the day you were day of the weeks have certain effects, either positive and negative on the activities or star of human beings. Hence they warn that there certain day ...
Read More »